Lúùkù 12:4 BMY

4 “Èmi sì wí fún yín ẹ̀yin ọ̀rẹ́ mi, ẹ má ṣe bẹ̀rù àwọn tí ó ń pa ara ènìyàn kú, lẹ́yìn èyí, wọn kò sì ní èyí tí wọ́n lè ṣe mọ́.

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:4 ni o tọ