Lúùkù 12:42 BMY

42 Olúwa sì dáhùn wí pé, “Ta ni olóòótọ́ àti ọlọ́gbọ́n ìríjú náà, tí olúwa rẹ̀ fi jẹ olórí agbo ilé rẹ̀, láti máa fi ìwọ̀n oúnjẹ wọ̀n fún wọn ní àkókò?

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:42 ni o tọ