Lúùkù 12:56 BMY

56 Ẹ̀yin àgàbàgebè! Ẹ̀yin le mòye ojú ọ̀run àti ti ayé. Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin kò mọ àkókò yìí?

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:56 ni o tọ