Lúùkù 12:7 BMY

7 Ṣùgbọ́n gbogbo irun orí yín ni a kà pé ṣánṣán. Nítorí náà kí ẹ má ṣe bẹ̀rù: ẹ̀yin ní iye lórí ju ológóṣẹ́ púpọ̀ lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 12

Wo Lúùkù 12:7 ni o tọ