Lúùkù 13:19 BMY

19 Ó dàbí hóró músítádì, tí ọkùnrin kan mú, tí ó sì sọ sínú ọgbà rẹ̀; tí ó sì hù, ó sì di igi ńlá; àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ń gbé orí ẹ̀ka rẹ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:19 ni o tọ