Lúùkù 13:24 BMY

24 “Ẹ làkàkà láti gba ojú ọ̀nà tóóró wọlé: nítorí mo wí fún yín, ènìyàn púpọ̀ ni yóò wá ọ̀nà láti wọ̀ ọ́, wọn kì yóò sì lè wọlé.

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:24 ni o tọ