Lúùkù 13:31 BMY

31 Ní wákàtí kan náà, díẹ̀ nínú àwọn Farisí tọ̀ ọ́ wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Jáde, kí ìwọ sì lọ kúrò níhín-ín yìí: nítorí Hẹ́rọ́dù ń fẹ́ pa ọ́.”

Ka pipe ipin Lúùkù 13

Wo Lúùkù 13:31 ni o tọ