Lúùkù 14:1 BMY

1 Nígbà tí ó wọ ilé ọ̀kan nínú àwọn olórí Farisí lọ ní ọjọ́ ìsinmi láti jẹun, wọ́n sì ń ṣọ́ ọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 14

Wo Lúùkù 14:1 ni o tọ