Lúùkù 14:14 BMY

14 Ìwọ ó sì jẹ́ alábùkún fún; nítori wọn kò ní ohun tí wọn ó fi san án fún ọ: ṣùgbọ́n a ó san án fún ọ ní àjíǹde, àwọn olóòótọ́.”

Ka pipe ipin Lúùkù 14

Wo Lúùkù 14:14 ni o tọ