Lúùkù 15:31 BMY

31 “Ó sì wí fún un pé, ‘Ọmọ, nígbà gbogbo ni ìwọ ń bẹ lọ́dọ̀ mi, ohun gbogbo tí mo sì ní, tìrẹ ni.

Ka pipe ipin Lúùkù 15

Wo Lúùkù 15:31 ni o tọ