4 “Ọkùnrin wo ni nínú yín, tí ó ní ọgọ̀rún-ún àgùntàn, bí ó bá sọ ọ̀kan nù nínú wọn, tí kì yóò sì tọ ipaṣẹ̀ èyí tí ó nù lọ, títí yóò fi rí i?
Ka pipe ipin Lúùkù 15
Wo Lúùkù 15:4 ni o tọ