Lúùkù 15:8 BMY

8 “Tàbí obìnrin wo ni ó ní fàdákà mẹ́wàá bí ó bá sọ ọ̀kan nù, tí kì yóò tan fìtílà, kí ó fi gbá ilé, kí ó sì wá a gidigidi títí yóò fi rí i?

Ka pipe ipin Lúùkù 15

Wo Lúùkù 15:8 ni o tọ