Lúùkù 16:3 BMY

3 “Ìríjú náà sì wí nínú ara rẹ̀ pé, ‘Èwo ni èmi ó ṣe? Nítorí tí olúwa mi gba iṣẹ́ ìríjú lọ́wọ́ mi: èmi kò lè walẹ̀; láti sàgbẹ̀ ojú ń tì mí.

Ka pipe ipin Lúùkù 16

Wo Lúùkù 16:3 ni o tọ