16 Ó sì wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀, ó ń dúpẹ́ ní ọwọ́ rẹ̀: ará Samáríà ni òun í ṣe.
Ka pipe ipin Lúùkù 17
Wo Lúùkù 17:16 ni o tọ