Lúùkù 17:29 BMY

29 Ṣùgbọ́n ní ọjọ́ náà tí Lọ́ọ̀tì jáde kúrò ní Ṣódómù, òjò iná àti súfúrù rọ̀ láti ọ̀run wá, ó sì run gbogbo wọn.

Ka pipe ipin Lúùkù 17

Wo Lúùkù 17:29 ni o tọ