Lúùkù 18:1 BMY

1 Ó sì pa òwe kan fún wọn nítorí èyí yìí pé, ó yẹ kí a má a gbàdúrà nígbà gbogbo, kí a má sì ṣàárẹ̀;

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:1 ni o tọ