Lúùkù 18:24 BMY

24 Nígbà tí Jésù rí i pé inú rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi, ó wí pé, “Yóò ti ṣòro tó fún àwọn tí ó ní ọrọ̀ láti wọ ìjọba Ọlọ́run!

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:24 ni o tọ