Lúùkù 18:29 BMY

29 Ó sì wí fún wọn pé, “Lóòótọ́ ni mo wí fún yín, kò sí ẹni tí ó fi ilé, tàbí aya, tàbí ará, tàbí òbí, tàbí ọmọ sílẹ̀, nítorí ìjọba Ọlọ́run,

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:29 ni o tọ