Lúùkù 18:32 BMY

32 Nítorí tí a ó fi lé àwọn aláìkọlà lọ́wọ́, a ó fi ṣe ẹlẹ́yà, a ó sì fi ṣe ẹ̀sín, a ó sì tutọ́ si i lára.

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:32 ni o tọ