Lúùkù 18:43 BMY

43 Lójúkan náà ó sì ríran, ó sì ń tọ̀ ọ́ lẹ́yìn, ó sì ń yin Ọlọ́run lógo àti gbogbo ènìyàn nígbà tí wọ́n rí i, wọ́n fi ìyìn fún Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:43 ni o tọ