Lúùkù 18:8 BMY

8 Mo wí fún yín, yóò gbẹ̀san wọn kánkán! Ṣùgbọ́n nígbà tí Ọmọ Ènìyàn bá dé yóò ha rí ìgbàgbọ́ ní ayé bí?”

Ka pipe ipin Lúùkù 18

Wo Lúùkù 18:8 ni o tọ