Lúùkù 19:14 BMY

14 “Ṣùgbọ́n àwọn ará ìlù rẹ̀ kórìíra rẹ̀, wọ́n sì rán ikọ̀ tẹ̀lé e, wí pé, ‘Àwa kò fẹ́ kí ọkùnrin yìí jọba lórí wa.’

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:14 ni o tọ