Lúùkù 19:33 BMY

33 Bí wọ́n sì ti ń tú ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà, àwọn Olúwa rẹ̀ bi wọ́n pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń tu kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà?”

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:33 ni o tọ