Lúùkù 19:42 BMY

42 Ó ń wí pé, “Ìbáṣepé ìwọ mọ̀, lóní yìí, àní ìwọ, ohun tí í ṣe tí àlààáfíà rẹ! Ṣùgbọ́n nísinsin yìí wọ́n pamọ́ kúrò lójú rẹ.

Ka pipe ipin Lúùkù 19

Wo Lúùkù 19:42 ni o tọ