39 Nígbà tí wọ́n sì ti ṣe nǹkan gbogbo tán gẹ́gẹ́ bí òfin Olúwa, wọ́n padà lọ sí Gálílì, sí Násárẹ́tì ìlú wọn.
Ka pipe ipin Lúùkù 2
Wo Lúùkù 2:39 ni o tọ