Lúùkù 2:51 BMY

51 Ó sì bá wọn sọ̀kalẹ̀ lọ sí Násárétì, sì fi ara balẹ̀ fún wọn: ṣùgbọ́n ìyá rẹ̀ pa gbogbo nǹkan wọ̀nyí mọ́ nínú ọkàn rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 2

Wo Lúùkù 2:51 ni o tọ