Lúùkù 20:1 BMY

1 Ní ijọ́ kan, bí ó ti ń kọ́ àwọn ènìyàn ní tẹ́ḿpìlì tí ó sì ń wàásù ìyìn rere, àwọn olórí àlùfáà, àti àwọn alàgbà dìde sí i.

Ka pipe ipin Lúùkù 20

Wo Lúùkù 20:1 ni o tọ