Lúùkù 20:35 BMY

35 Ṣùgbọ́n àwọn tí a kà yẹ láti jogún ìyè ayérayé náà, àti àjíǹde kúrò nínú òkú, wọn kì í gbéyàwó, wọn kì í sì í fa ìyàwó fún-ni.

Ka pipe ipin Lúùkù 20

Wo Lúùkù 20:35 ni o tọ