Lúùkù 21:21 BMY

21 Nígbà náà ni kí àwọn tí ń bẹ ní Jùdéà sá lọ sórí òkè; àti àwọn tí ń bẹ láàrin rẹ̀ kí wọn jáde kúrò; kí àwọn tí ó sì ń bọ̀ ní ìgbéríko má ṣe wọ inú rẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Lúùkù 21

Wo Lúùkù 21:21 ni o tọ