Lúùkù 22:45 BMY

45 Nígbà tí ó sì dìde kúrò ní ibi àdúrà, tí ó sì tọ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá ó bá wọn, wọ́n ń sùn fún ìbànújẹ́.

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:45 ni o tọ