Lúùkù 22:54 BMY

54 Wọ́n sì gbá a mú, wọ́n sì fà á lọ, wọ́n sì mú un wá sí ilé olórí àlùfáà. Ṣùgbọ́n Pétérù tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní òkèrè.

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:54 ni o tọ