Lúùkù 22:56 BMY

56 Ọmọbìnrin kan sì rí i bí ó ti jókòó níbi ìmọ́lẹ̀ iná náà, ó sì tẹjúmọ́ ọn, ó ní, “Eléyìí náà wà pẹ̀lú rẹ̀.”

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:56 ni o tọ