Lúùkù 22:64 BMY

64 Nígbà tí wọ́n sì dì í ní ojú, wọ́n lù ú níwájú, wọ́n ń bi í pé, “Sọ tẹ́lẹ̀! Ta ni ó lù ọ́?”

Ka pipe ipin Lúùkù 22

Wo Lúùkù 22:64 ni o tọ