Lúùkù 23:48 BMY

48 Gbogbo ìjọ ènìyàn tí ó péjọ láti rí ìran yìí, nígbà tí wọ́n rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀ wọ́n lu ara wọn ní oókan àyà, wọ́n sì padà sí ilé.

Ka pipe ipin Lúùkù 23

Wo Lúùkù 23:48 ni o tọ