Lúùkù 23:7 BMY

7 Nígbà tí ó sì mọ̀ pé ará ilẹ̀ Hẹ́rọ́dù ni, ó rán an sí Hẹ́rọ́dù, ẹni tí òun tìkárarẹ̀ wà ní Jerúsálémù ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Lúùkù 23

Wo Lúùkù 23:7 ni o tọ