Lúùkù 24:10 BMY

10 Màríà Magaléènì, àti Jóánnà, àti Màríà ìyá Jákọ́bù, àti àwọn mìíràn pẹ̀lú wọn sì ni àwọn tí ó ròyìn nǹkan wọ̀nyí fún àwọn àpósítélì.

Ka pipe ipin Lúùkù 24

Wo Lúùkù 24:10 ni o tọ