Lúùkù 3:15 BMY

15 Bí àwọn ènìyàn sì ti ń retí, tí gbogbo wọn sì ń rò nínú ara wọn nítorí Jòhánù, bí òun ni Kírísítì bí òun kọ́;

Ka pipe ipin Lúùkù 3

Wo Lúùkù 3:15 ni o tọ