Lúùkù 3:19 BMY

19 Ṣùgbọ́n nígbà ti Jòhánù bú Hẹ́rọ́dù tetírakì, tí ó bá wí nítorí Hérọ́díà aya Fílípì arákùnrin rẹ̀, àti nítorí ohun búburú gbogbo tí Hẹ́ródù tí ṣe,

Ka pipe ipin Lúùkù 3

Wo Lúùkù 3:19 ni o tọ