26 Tí í ṣe ọmọ Máátì,tí í ṣe ọmọ Matatíà, tí í ṣe ọmọ Síméì,tí í ṣe ọmọ Jósẹ́fù, tí í ṣe ọmọ Jódà,
27 Tí í ṣe ọmọ Jóánà, tí í ṣe ọmọ Résà,tí í ṣe ọmọ Sérúbábélì, tí í ṣe ọmọ Sítíélì,tí í ṣe ọmọ Nérì,
28 Tí í ṣe ọmọ Melíkì,tí í ṣe ọmọ Ádì, tí í ṣe ọmọ Kòsámù,tí í ṣe ọmọ Élímadámù, tí í ṣe ọmọ Érì,
29 Tí í ṣe ọmọ Jósúà, tí í ṣe ọmọ Élíásérì,tí í ṣe ọmọ Jórímù, tí í ṣe Màtátì,tí í ṣe ọmọ Léfì,
30 Tí í ṣe ọmọ Síméónì,tí í ṣe ọmọ Júdà, tí í ṣe ọmọ Jóséfù,tí í ṣe ọmọ Jónámù, tí í ṣe ọmọ Élíákímù,
31 Tí í ṣe ọmọ Méléà, tí í ṣe ọmọ Méná,tí í ṣe ọmọ Mátatà, tí í ṣe ọmọ Nátanì,tí í ṣe ọmọ Dáfídì,
32 Tí í ṣe ọmọ Jésè,tí í ṣe ọmọ Óbédì, tí í ṣe ọmọ Bóásì,tí í ṣe ọmọ Sólómónì, tí í ṣe ọmọ Náásónì,