33 Tí í ṣe ọmọ Ámínádábù, tí íṣe ọmọ Rámù,tí í ṣe ọmọ Ésírónì, tí í ṣe ọmọ Fárésì,tí í ṣe ọmọ Júdà.
34 Tí í ṣe ọmọ Jákọ́bù,tí í ṣe ọmọ Ísáákì, tí í ṣe ọmọ Ábúráhámù,tí í ṣe ọmọ Térà, tí í ṣe ọmọ Náhórì,
35 Tí í ṣe ọmọ Sárúgù, tí í ṣe ọmọ Rágáù,tí í ṣe ọmọ Fálékì, tí í ṣe ọmọ Ébérì,tí í ṣe ọmọ Sélà.
36 Tí í ṣe ọmọ Kénánì,tí í ṣe ọmọ Árífásádì, tí í ṣe ọmọ Sémù,tí í ṣe ọmọ Nóà, tí í ṣe ọmọ Lámékì,
37 Tí í ṣe ọmọ Mètúsélà, tí í ṣe ọmọ Énókù,tí í ṣe ọmọ Járédì, tí í ṣe ọmọ Máléléénì,tí í ṣe ọmọ Kénánì.
38 Tí í ṣe ọmọ Énósì,tí í ṣe ọmọ Sétì, tí í ṣe ọmọ Ádámù,tí í ṣe ọmọ Ọlọ́run.