1 Jésù sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́, ó padà ti Jọ́dánì wá, a sì ti ọwọ́ Ẹ̀mí darí rẹ̀ sí ijù;
Ka pipe ipin Lúùkù 4
Wo Lúùkù 4:1 ni o tọ