Lúùkù 4:20 BMY

20 Ó sì pa ìwé náà dé, ó fi í fún ìránṣẹ́, ó sì jókòó. Gbogbo àwọn tí ó ń bẹ nínú sínágọ́gù sì tẹjúmọ́ ọn.

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:20 ni o tọ