Lúùkù 4:27 BMY

27 Adẹ́tẹ̀ púpọ̀ ní sì ń bẹ ní Ísírẹ́lì nígbà wòlíì Èlíṣà; kò sì sí ọ̀kan nínú wọn tí a wẹ̀nùmọ́, bí kò ṣe Námánì ará Síríà.”

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:27 ni o tọ