Lúùkù 4:29 BMY

29 Wọ́n sì dìde, wọ́n tì í sóde sí ẹ̀yìn ìlú, wọ́n sì fà á lọ sí bèbè òkè níbi tí wọ́n gbé tẹ ìlú wọn dó, kí wọn bá à lè taari rẹ̀ ní ògèdèǹgbé.

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:29 ni o tọ