Lúùkù 4:38 BMY

38 Nígbà tí ó sì dìde kúrò nínú sínágọ́gù, ó sì wọ̀ ilé Símónì lọ; ibà sì ti dá ìyá ìyàwó Símónì gúnlẹ̀; wọ́n sì bẹ̀ ẹ́ nítorí rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:38 ni o tọ