Lúùkù 4:40 BMY

40 Nígbà tí oòrun sì ń wọ̀, àwọn ènìyàn mú àwọn aláìsàn tó ní onírúurú àìsàn wá sọ́dọ̀ Jésù; ó sì fi ọwọ́ lé olúkúlùkù wọn, ó sì mú wọn láradá.

Ka pipe ipin Lúùkù 4

Wo Lúùkù 4:40 ni o tọ