Lúùkù 5:11 BMY

11 Nígbà tí wọ́n sì ti mú ọkọ̀ wọn dé ilẹ̀, wọ́n fi gbogbo rẹ̀ sílẹ̀, wọ́n sì tọ̀ ọ́ lẹ́yìn lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:11 ni o tọ