Lúùkù 5:13 BMY

13 Jésù sì na ọwọ́ rẹ̀, ó fi kàn án, ó ní, “Mo fẹ́, ìwọ di mímọ́!” Lójúkan náà ẹ̀tẹ̀ sì fi í sílẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:13 ni o tọ