Lúùkù 5:25 BMY

25 Ó sì dìde lọ́gán níwájú wọn, ó gbé ohun tí ó dùbúlẹ̀ lé, ó sì lọ sí ilé rẹ̀, ó yin Ọlọ́run lógo.

Ka pipe ipin Lúùkù 5

Wo Lúùkù 5:25 ni o tọ