29 Léfì sì ṣe àṣè ńlá kan fún Jésù ní ilé rẹ̀, ọ̀pọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn mìíràn sì ń jẹun pẹ̀lú wọn.
Ka pipe ipin Lúùkù 5
Wo Lúùkù 5:29 ni o tọ